Welcome to Watch9jaHOME | ARTISTES | NIGERIAN | FOREIGN | FREEBEATS | MOVIES | VIDEOS | RELATIONSHIP

SEARCH CONTENTS (Use Name Or Title)Slimcase – Lamba Xtra

Download this track by Slimcase which he titled Lamba Xtra. Oluwafemi Oladapo, professionally Known as Slimcase is Nigerian artist, he is a singer, songwriter, entertainer, stage performer and a recording artists. He was born on 22 August 1982, in Ikorodu Lagos State Nigeria. Use the link below to stream and download Lamba Xtra by Slimcase 

WATCH VIDEO

Lyrics Of Lamba Xtra by Slimcase

Omi gbona boso lọrun edie
Edie saporo zagazege zegezigi rosu
Raka mailo
Mix Benson mo loud yẹn ki everything kon le

Oya gbakosun
Gba koje
Gbakosun
Gba koje
E se ma gbakosun
Mr man gba koje
Wọn ní gbakosun
File Azaman gba koje

Omo to shashe dede lo n gbo pe dede
To n gbowo wire gbo gboun side se gbe ivy
Oun order casket
Casket one casket two
Gbomo one bomo two wonu yara

O fe fagbo jẹun dobo
Fagbo jẹun dobo
Fagbo jẹun dobo
Fagbo jẹun dobo
To ba n gbo fagbo jẹun dobo
Fagbo jẹun dobo
O fe fagbo jẹun dobo okay
Fagbo jẹun dobo
Obinrin dudu obinrin pupua
Obinrin dudu obinrin pupua
Oloun ma ja ri ja obinrin Otunba lamba
Oloun ma ja ri ja obinrin zege zige zego

Oya gbakosun Wiili gba koje
Gbakosun IBD dende gba koje
O se ma gbakosun ose Larry Gaaga gba koje
Wonni gbakosun file Azaman gba koje

Onilu yí ọ káre lulu sì mi nibadi
Onilu yí ọ káre lulu sì mi lulu sì mi lulu sì mi
Lulu sì mi nibadi ehhhh
Sunday Bankole ma pami
Pata oloso ko kin nisimi
lleke oloso ko kin nisimi
Bo sen bo lon wo lon bo lon wol
Ileke mami furo má gbọn
Ileke mami furo ma gbọn
Eruku ganja ezaa aa

To ba n gbo eba logbe jọ
Eba lomo ton tí la la lọ lo
Lati kí bo lọ lọ
Towo bo tise bo gbenu si lari mo egbee

Wa ma gbo egusi nie jo
Egusi le ni ti o ja
Ẹniti to waja o wan wa ẹni ti o ja
Lọ fin pee ni eerrm wa magbo
Eba lọn wa egusi
Eba lon wa egusi
Eba lon wa shayo
Ele lon wa olowo
Gbakosun ọba gold gba koje ehhee
Gbakosun padi oosaa gba koje file
E se maan gbakosunspirituale gba koje ahhah
Won ni gbakosun Lanre typical gba koje

Quality Lee abakaka kii
O mọ pe iwọ nikan mo le gboti mi fun nau omọ iya mi
To ba ti de Istanbul bami ki Kay bami ki Jide ọtí yẹ ẹ
Dbreeze Monarch owo boxing
Dasi won kon ma baja leni
Azaman

Download Mp3 Here


| October 5, 2021.

Tags:

Categories: Naija Music

0 Comments

LEAVE A COMMENT

Type Name Below

Type Comment Below

« | »